HYMN 248

C.M.S. 151 t.H.C 133. C.M (FE 268)
"Omokunrin tujuka, a dari ese re ji o" 
- Matt 9:21. JESU mi, mu mi gb'ohun Re

   S'oro alafia;

   Ghogbo ipa mi y'o dalu 

   Lari yin Ore Re.


2. Fi iyonu pe mi l'omo 

   K’ o si dariji mi;

   Ohun na yio dunmo mi 

   B‘iro orin orun.


3. Ibikibi t'o to mi si, 

   L’emi o f' ayo lo 

   Tayotayo l’emi o si 

   Dapo m'awon oku.


4. Gba eru ebi ba koja 

   Eru mi ko si mo

   Owo t’o fun 'dariji ka, 

   Y'o pin ade iye. Amin

English »

Update Hymn