HYMN 250

C.M.S 155 H.C 148 S.M (FE 270)
"Ranti Oluwa" - Ps. 106: 41. JESU, jo ranti mi

   K'O si w'ese mi nu 

   Gba mi low‘ese 'binibi 

   Si we okan mi mo.


2. Jesu, jo ranti mi

   Em' eni nilara

   Ki mse ‘ranse t'o n‘ife Re 

   Ki m'to ‘simi Re wo.


3. Jesu, jo ranti mi

   Muse je ki nsako

   N’nu damu on okun aiye 

   F'ona orun han mi.


4. Jesu, jo ranti mi,

   Gba gbogbo re koja

   Ki nle r’ogo ainipekun 

   Ki nsi le ba O yo.


5. Jesu, jo ranti mi

   Ki nle korin loke

   Si baba, Emi ati Re 

   Orin ‘yin at' ife. Amin

English »

Update Hymn