HYMN 254

Tune: C.M.S 161 K. 523. t. H. C. 
17 L.M (FE 274)
"Abo mi mbe lodo Olorun” - Ps. 7:101. PELU mi nibiti mo nlo 

   Ko mi l’ohun t’emi o se

   Sa gbo aro at’oro mi 

   K‘o f'ese mi le ona Re.


2. Fi opo ife Re fun mi 

   Ma se alabo mi lailai 

   Fi edidi Re s’aiya mi 

   Je ki Emi Re pelu mi.


3. Ko mi bi a ti gbadura

   Jeki emi gba Iwo gbo

   Ki nkorira nkan t’ O ko fe 

   K’emi si fe ‘hun ti O fe. Amin

English »

Update Hymn