HYMN 26

E.O. 22, 6s 8s (FE 43)
Ohun Orin: "Eyo Jesu joba"


1. GBOGBO ara aiye

   T'o wa ninu ese

   T’o nb ojo ‘simi je

   Oluwa nke si yin.

Egbe: Egbe Kerubu, Serafu 

      Sofamiye p’Oluwa mbo. 2ce


2. E damure giri,

  Kerubu, Serafu

  E funpe na kikan

  Nipa t‘ojo ‘simi

Egbe: Egbe Kerubu, Serafu...


3. Enyin Onigbagbo 

   L'awon Imale nwo 

   At‘awon Keferi

   Nipa t'ojo 'simi.

Egbe: Egbe Kerubu, Serafu...


4. E mura Iati ba

   Oluwa yin laja

   Mase f'aye sile 

   F‘esu lati mi yin.

Egbe: Egbe Kerubu, Serafu...


5. Toro ida Emi,

   Lowo Olorun re,

   Pelu bata irin

   Lati t‘esu mole.

Egbe: Egbe Kerubu, Serafu...


6. Oluwa fun wa se,

   K‘a p‘ojo mimo mo

   Ka le ri igbala

   Nikehin ojo wa.

Egbe: Egbe Kerubu, Serafu... Amin

English »

Update Hymn