HYMN 261

C.M.S 177 H.C 305 11s (FE 281)
"On le pa eyiti mo fi Ire e lowo mo”
 - 2 Tim. 1:121. JESU, emi o fi okan mi fun O 

   Mo jebi, mo gbe, sugbon

   ‘Wo le gba mi

   L'aiye ati l'orun, ko seni bi Re 

   lwo ku f’elese, ferni na pelu.


2. Jesu, mo le simi le oruko Re 

   Ti Angeli wa so, l‘ojo ibi Re 

   Yi ti‘a ko ti o han lor' agbelebu

   Ti elese si ka, nwon si teriba.


3. Jesu, emi ko le saigbekele O,

   Ise Re l’aiye kun f’anu at'ife 

   Elese yi O ka, adete ri O,

   Ko s'eni buruju, t’Iwo ko le gba.


4. Jesu mo Ie gbeke mi le oro Re

   Bi ngo tile gbo ohun anu Re ri 

   Gbat‘ Emi Re nto ni, o ti dun po to 

   Ki nsa f‘ibarale k'eko lese Re.


5. Jesu toto-toto, mo gbekele O, 

   Enikeni t‘o wa, Wo ki o ta nu 

   Oto ni ‘Ieri Re, owon l' eje Re; 

   ‘Wonyi n'igbala mi, ‘Wo 

   I‘Olorun mi. Amin

English »

Update Hymn