HYMN 263

H.C. 171 8s 6s 4 (FE 283)
"lsreali, yipada si Oluwa Olorun re"
- Hos. 14:11. PADA asako s’ile re 

   Baba re l'o npe o 

   Mase alarinkiri mo

   Nin‘ese at’osi 

   Pada, pada. 


2. Pada asako s’ile re

   Jesu l‘o sa npe o

   Emi pelu ljo si npe

   Yara sa asala 

   Pada, pada.


3. Pada asako s'ile re 

   Were ni, b’o ba pe 

   Ko si 'dariji n‘iboji 

   Ojo anu kuru 

   Pada, pada. Amin

English »

Update Hymn