HYMN 264

H.C.176 D.7s (FE 284)
"Emi o ha si jowo re Iowo" Hos - 11:81. IBU anu! O le je

   P’ anu si mbe fun mi 

   Olorun le mu suru

   F’ emi olori elese? 

   Mo ti ko or‘ofe Re 

   Mo bi n'nu lojukoju 

   Nko f‘eti si ipe Re 

   Mo so ninu I'ainiye.


2. Mo tan a ni suru to 

   Sibe o si da mi si

   O nke, ‘Ngo se jowo re 

   Sa gba ago igbala 

   Olugbala mi nduro

   O si nfi ogbe Re han 

   Mo mo, ife l‘Olorun 

   Jesu, nsun, O feran mi.


3. Jesu, dahun lat‘oke 

   Ife k'iwa Re gbogbo? 

   ‘Wo ki y'o dariji mi 

   Ki nwole ii ese Re? 

   Bi m'ba mo inu Re re 

   B’Iwo 'ba se alanu 

   F’anu deti Re sile 

   Dariji, k'o si gba mi.


4. F‘oju iyonu wo mi 

   Fi wiwo oju pe mi

   Mu okan okuta ro 

   Yipada, ro mi lokan 

   Mu’mi ronupiwada 

   Je ki ngbawe f’ese mi 

   Ki nsi kanu ise mi

   Ki ngbagbo, ki nye dese. Amin

English »

Update Hymn