HYMN 272

CMS 170 t.H.C. 167 S.M (FE 292)
"Ese ti enyin fi se ojo be, enyin
onigbagbo kekere?" - Matt 8:261. SA dake okan mi 

   Oluwa re wa mbe 

   Enit' o ti se ileri 

   Yio fe mu u se.


2. On ti fa O lowo 

   Omu o de ‘hin yi 

   Y‘o pa o mo la ewu ja 

   Tit‘ opin aiye re.


3. Nigbat‘iwo ti bo

   Sinu wahala ri 

   lgbe re na ki On ha gbo 

   T‘o si yo O kuro?


4. B’ona ko tile dan

   Yio mu o de ‘le

   Sa ti wahala aiye tan

   O san fun gbogbo re. Amin

English »

Update Hymn