HYMN 273

C.M.S. 171 H.C 149 C.M (FE 293) 
“Ongbe Olurun ngbe okan" - Ps. 42:21. BI agborin ti nmi hele 

   S'ipa Odo omi

   Beni okan mi nmi si O 

   Iwo Olorun mi.


2. Orungbe Re ngbe Okan mi 

   Olorun alaye;

   Nigbawo ni ngo r'Oju Re, 

   Olorun Olanla?


3. Okan mi o se rewesi 

   Gbekele Olorun 

   Eniti y'o so ekun re 

   D’orin ayo fun o.


4. Y’o ti pe to, Olorun mi, 

   Ti ngo d'eni gbagbe?

   T’ao ma ti mi sihin, sohun 

   B‘eni ko ni ‘bugbe.


5. Okan mi o so rewesi? 

   Gbagbo ‘wo o si ko 

   Orin iyin s’Olorun re 

   Orisun emi re. Amin

English »

Update Hymn