HYMN 274

(FE 296)
“Anu ni emi nfe" - Matt. 9:131. B’ERU ese re ba nwo o Iorun 

   Pe Jesu wole Okan re

   B'o ndaniyan isoji Okan re 

   Pe Jesu wole okan re.

Egbe: Le'yemeji re sonu 

      Ba Oluwa re laja

      Si okan re paya fun 

      Pe Jesu wole okan re.


2. Bi o ba nwa iwenumo kiri 

   Pe Jesu wole okan re

   Oni ‘wenumo ko jina si o 

   Pe Jesu wole okan re.

Egbe: Le'yemeji re sonu...


3. B'lgbi wahala ba ngba o kiri 

   Pe Jesu wole okun re

   B‘afo ba wa ti aiye ko le di 

   Pe jesu wole okan re. 

Egbe: Le'yemeji re sonu...


4. Bi ore t‘o gbekele ba da o 

   Fe Jesu wole okan re

   On nikan ni Olubanidaro 

   Pe Jesu wole okan re.

Egbe: Le'yemeji re sonu...


5. B’o nfe korin awon alabukun 

   Pe Jesu wole okan re

   Bi o nfe wo agbala isimi 

   Pe Jesu wole okan re.

Egbe: Le'yemeji re sonu 

      Ba Oluwa re laja

      Si okan re paya fun 

      Pe Jesu wole okan re. Amin

English »

Update Hymn