HYMN 277

H.C 117 6s (FE 297)
“ljoba re de" - Matt. 6:101. KRIST’ ki 'joba Re de 

   Ki ase Re bere

   F’opa-irin Re fo 

   Gbogbo ipa ese.


2. ljoba ife da

   Ati t'alafia

   Gba wo ni irira 

   Yio tan bi t'orun?


3. Akoko na ha da 

   T’ote yio pari 

   lka at‘ireje 

   Pelu ifekufe?


4. Oluwa jo, dide

   Wa n’nu aghara Re

   Fi ayo fun awa 

   Ti o ns‘aferi Re.


5. Eda ngan oko Re 

   Koko nje agbo Re 

   lwa ‘tiju pupo 

   Nfihan pe ‘fe tutu.


6. Okun bole sibe 

   Ni ile keferi

   Dide 'Rawo oro

   Dide, mase wo mo. Amin

English »

Update Hymn