HYMN 280

T.H.C. 150 C.M (FE 300) 
"Gbo adura mi Oluwa" - Ps.102:11. BABA alanu t'o fe wa 

   Mo gb’okan mi si O

   lpa Re t’o po l'o gba wa; 

   Awa nkorin si O.


2. Tire papa l’awa fe ese 

   Gb’okan wa fun ebo; 

   O da wa, o si tun wa bi 

   A f' ara wa fun O.


3. Emi Mimo, wa sodo mi, 

   F'ife Oluwa han

   Fun mi k‘emi k’o le ma rin 

   N’ife Oluwa mi. Amin

English »

Update Hymn