HYMN 281

CM.S. 579 C.M (FE 301) 
“Jesu, Baba sanu fun wa:” - Luku 17:131. ESE mi po bi irawo 

   Bi‘yanrin let‘okun

   Sugbon iyonu Olorun 

   O p’apoju be lo.


2. Manase, Paul, On Magdalen 

   lwo dariji won

   Mo ti ka mo si gbagbo pe

   O ti dariji mi. Amin

English »

Update Hymn