HYMN 282

C.M.S 578 K. 616 8s.7s (FE 302) 
"Ife ni Olorun" - 1 John 41. IFE l‘Olorun, anu Re 

   Tan si ona wa gbogbo 

   O fun wa ni alafia

   Ife ni Olorun wa.


2. Iku ndoro pupopupo 

   Enia si ndibaje 

   Sugbon anu Re wa titi 

   lfe ni Olorun wa.


3. Lakoko t’o dab’o sokun 

   A nri Ore Re daju

   O tan imole Re fun wa 

   lfe ni Olorun wa.


4. O so 'reti, at‘itunu

   Mo aniyan aiye wa,

   Ogo Re ntan nibi gbogbo 

   lfe ni Olorun wa. Amin

English »

Update Hymn