HYMN 286

C.M.S 195 H.C 181 L.M (FE 307) 
“Ali 11th 0101110,Re. ma gesin I n "
Ps. 45:4 ‘1. MA gesin lo I‘olanla Re,

   Gbo! gbogb’aiye nke “Hosanna” 

   Olugbala, ma lo pele

   Lori im'ope at‘aso.


2. Ma gesin lo l’olanla Re, 

   Ma f ’irele gesin lo ku 

   Kristi, ‘segun Re bere na 

   Lori ese ati iku.


3. Ma gesin lo l'olanla Re, 

   Ogun Angeli lat‘orun 

   Nf‘iyanu pelu ikanu 

   Wo ebo to sunmole yi.


4. Ma gesin lo l'olanla Re, 

   lja ikehin na de tan 

   Baba, lor‘ite Re l’orun 

   Nreti ayanfe Omo Re.


5. Ma gesin lo l'olanla Re, 

   Ma f‘irele gesin lo ku 

   F'ara da irora f’eda 

   Lehin na, nde k’O ma joba. Amin

English »

Update Hymn