HYMN 287

C.M.S 194 H.C 80 D.7s 6s. (FE 308)
"Hosanna fun Omo Dafidi" - Matt. 21:91. GBOGB' ogo, iyin, ola 

   Fun O, Oludande 

   S'Eni t’awon omode

   Ko Hosanna didun! 

   ‘Wo! l‘Oba lsreali 

   Om'Alade Dafidi 

   T'o wa l‘Oko Oluwa 

   Oba Olubukun. 

Egbe: Gbogb'ogo, iyin, ola 

      Fun O, Oludande,

      S'Eni t'awon omode 

      Ko Hosanna didun.


2. Egbe awon Maleka 

   Nyin O Ioke giga 

   Awa at'eda gbogbo 

   Si dapo gberin na. 

Egbe: Gbogb'ogo, iyin...


3. Awon Hebru lo saju 

   Pelu imo ope

   lyin, adua at'orin 

   L‘a mu wa ‘waju Re.

Egbe: Gbogb'ogo, iyin...


4. Si O saju iya Re 

   Nwon korin iyin won 

   Wo t'a gbe ga nisisyi 

   L‘a nkorin iyin si. 

Egbe: Gbogb'ogo, iyin...


5. ‘Wo gba orin iyin won 

   Gb'adura t’a mu wa 

   Wo ti nyo s’ohun rere 

   Oba wa Olore.

Egbe: Gbogb'ogo, iyin, ola 

      Fun O, Oludande,

      S'Eni t'awon omode 

      Ko Hosanna didun. Amin

English »

Update Hymn