HYMN 290

C.M.S 193 K. 241 t.H.C 16, L.M
(FE 311)
'O ye ki a se ariya, ki a si yo"
- Luku 15:221. TANl le so t‘ayo ti mbe 

   Ni agbala Paradise 

   Gba t‘amusua ba pada 

   T‘o si di arole ogo?


2. Ni ayo ni Baba fi wo 

   Eso ife Re ailopin 

   L’ayo l'Omo we Ie t’O ri 

   Ere iwaya-ija Re.


3. Tayotayo l’Emi si nwo 

   Okan mimo t'o n so dotun 

   Awon mimo at‘Angel nko 

   Orin Igbala Oba won. Amin

English »

Update Hymn