HYMN 291

t.H.C. 68 S.M (FE 312) 
"Ni pepe Re wonni, Oluwa awon
omo Ogun" - Ps. 84:31. SI pepe Oluwa,

   Mo mu ‘banuje wa

   Wo ki o f'anu tewogba, 

   Ohun alaiye yi?


2. Kristi Odagutan

   Ni igbagbo mi nwo 

   Wo le ko hun alaiye yi? 

   Wo o gba ebo mi.


3. Gbati Jesu mi ku

   A te ofin l'orun

   Ofin ko ba mi l’eru mo 

   Toripe Jesu ku. Amin

English »

Update Hymn