HYMN 293

K. 154 t.H.C 94 S.M (FE 314)
"Eje Jesu Kristi Omo re ni nwe 
wa nu kuro ninu ese wa gbogbo"
 - 1 John 1:71. GBOGBO eje eran,

   Ti pepe awon Ju

   Ko le f'okan l'alafia 

   Ko le we eri nu.


2. Kristi Od'agutan 

   M‘ese wa gbogbo lo 

   Ebo t‘o ni oruko nla 

   T'o ju eje won lo.


3. Mo f‘igbagbo gb‘owo 
  
   Le ori Re owon 

   B'enit’o ronupiwada 

   Mo jewo ese mi.


4. Okan mi npada wo 

   Eru t'lwo ti ru

   Nigbati a kan O mo ‘gi 

   Ese re wa nibe.


5. Awa nyoi ni ‘gbagbo 

   Bi egun ti kuro

   Awa nyin Odo-agutan, 

   A nkorin ife re. Amin

English »

Update Hymn