HYMN 30

C.M.S 30, t.H.C. 15, 6s. (FE 47)
"0ni Ii ojo isimi ti Oluwa" - Eks 16:25


1. JESU, afe pade,

   L'ojo Re Mimo yi

   A si y‘ite Te ka 

   L'ojo Re mimo yi 

   ‘Wo Ore wa orun 

   Adura wa mbo wa,

   Bojuwo emi wa,

   L'ojo Re mimo yi.


2. A ko gbodo lora, 

   L‘ojo Re mimo yi; 

   Li eru a kunle, 

   Lojo Re mimo yi 

   Ma taro ise wa, 

   K'Iwo ko si ko wa 

   K'a sin O b‘o ti ye 

   L’ojo Re mimo yi.


3. A teti s’oro Re 

   L'ojo Re mimo yi, 

   Bukun oro t'a gbo 

   L’ojo Re mimo yi, 

   Ba wa lo gbat’ a lo 

   F’ore Igbala Re,

   Si aiya wa gbogbo, 

   L'ojo Re mimo yi. Amin

English »

Update Hymn