HYMN 300

t.H. C 173 (FE 321) Tune: LM
“O si ti se alafia nipa eje agbelebu Re"
- Kol. 1:201. AGBELEBU ni ere mi 

   Nibe ni a rubo fun mi 

   Nibe l'a kan Oluwa mo 

   Nibe l‘Olugbala mi ku.


2. Kini o le fa okan Re 

   Lati teri gba iya mi? 

   Aimohun na daju l'o se

  T'okan mi tutu be si O.


3. Aifohun na oju ti mi 

   Niwaju Jesu mimo mi

   T’o ta ‘je Re sile fun mi, 

   ‘Tori o fe mi l'afeju. Amin

English »

Update Hymn