HYMN 302

1. LORI oke lehin 'lu l‘agbelebu 

   kan wa 

   Apere iya at‘egan

  Okan mi fa sibe, s’Olufe mi owon 

  T‘a pa f’ese gbogbo aye.

Egbe: Emi yoo gbe agbelelu re 

      Titi n fo fi pari ajo mi

      Emi o ro m agbelebu naa 

      K’emi le de ade n'ikehin.


2. Agbelebu naa t’awon araye kegan 

   Oun l'o ni ewa l‘oju mi,

   ‘Tori Om’Olorun, bo ogo Re sile 

   O si ti ru u lo si Kalfari.

Egbe: Emi yoo gbe agbelelu re...


3. L'ar'agbelebu naa, t'eje mimo 

   san si 

   Mo r‘ewa iyanu nibe

   Tori pe lori re, Jesu jiya o ku

   O dariji, o we mi mo.

Egbe: Emi yoo gbe agbelelu re...


4. Emi yoo j’olooto s’Emiti t’O 

   ku fun mi 

   Ngo f’ayo r’egan oun tiju

   Nigboose yoo pe mi lo le ayeraye

   Ki n le n‘ipin ninu ogo Re.

Egbe: Emi yoo gbe agbelelu re 

      Titi n fo fi pari ajo mi

      Emi o ro m agbelebu naa 

      K’emi le de ade n'ikehin. Amin

English »

Update Hymn