HYMN 309

ORIN ASALE AJINDE
309. (FE330)
"Niboniiwowa."- Gen.3:91. O wa nibe ‘gbati Judasi 

   fi ban. 2ce

Egbe: Bo sepe mo wa nibe, 

      anu a se mi,

      O wa nibe ‘gbati Judasi fihan.


2. O wa nibe ‘gbati Peter se 

   Jesu. 2ce

Egbe: Bo sepemo wa nibe anu 

      a se mi &c.


3. O wa nibe ‘gbati Akuko 

   siko. 2ce

Egbe: Ba sepe mo wa nibe, 

      anu a semi &c.


4. O wa nibe‘gbati won da, 

   Jesu l’ebi. 2ce

Egbe: Bo sepe mo wani be, 

      ara mi a gbon &c.


5. O we nibe ‘gba won f’ egun

   de l’ ori. 2ce

Egeb: Bo sepe mo wa nibe 

      emi a sokun &c.


6. O wa nibe‘gba won kan 

   m’ agbelebu. 2ce

Egbe: Bo sepe mo wa nibe 

      emi a sokun &c.


7. O wa nibe ‘gba t’okukun 

   Su bole. 2ce

Egbe: Bo sepe mo wa nibe, 

      eru a bami &.


8. O wa nibe’gbati Kerubu 

   To wa. 2ce

Egeb: Bo sepe mo wa nibe

      ayo mi a kun &c.


9. O wa nibe‘gbati Serafu 

   Towa. 2ce

Egbe: Bo sepe mo wa nibe, 

      ayo mi a kun & c.


10. O wa nibe ‘gba won f’ Oko 

    gun l’egbe. 2ce 

Egbe: Bo sepe mo wa nibe 

      emi a sokun &c.


11. O wa nibe ‘gbati aso, 

    Tempili fa ya. 2ce 

Egbe: Bo sepe mo wa nibe,

      Eru a ba le mi & c.


12. O wa nibe ‘gbati Jesu ji 

    dide. 2ce

Egbe: Bo sepe mo wa nibe 

      ayo mi a kun &c. Amin

English »

Update Hymn