HYMN 311

1. OLUWA mi ha ta eje 

   Re sile, O si ku?

   O wa f’ori ogo Re ni 

   Sile fun ‘ru emi?

Egbe: Nibi agbelebu ni mo ko r’imole 

      Nibe I’eru okan mi si fo lo

      (si fo Io)

      Nibe nipa igbagbo mo riran 

      N'sinyi mo wa I 'alaafia titi.


2. Nje n’tori ‘se ‘bi mi l’O se 

   Kerora lor’igi'?

   Oore-ofe iyanu ni

   At‘ife ailegbe!


3. OOrun wo s’inu okunkun 

   O b’ogo Re mole

   ‘Gba ti Kristi, Eleda ku 

   Fun ese eniyan.


4. Sugbon omije ko le san 

   Gbese ‘f'e ti mo je 

   Oluwa, mo f‘ara mi ‘le 

   Fun ife Re nikan. Amin

English »

Update Hymn