HYMN 312

C.M.S 205 O. t.H.C. 96 D.7s 6s. 
(FE 333)
"Olorunfe araiye lobe ge. " John 3:161. OLORUN fe araye,

   O fe tobe ge:

   T' O ran omo Re w' aiye 

   T' Oku fun elese,

   Olorun ti mo tele,

   Pe, emi o se si

   Ofin ati Ife Re,

   lwo ha fe mi bi?


2. Loto, Olorun fe mi, 

   Ani ani ko si,

   Awon t' o yipada si, 

   Igbala ni nwon ri 

   Wo! Jesu Kristi jiya, 

   Igi I‘a kan A mo,

   Wo ! eje Re ti o san, 

   Wo! ro! ma dese mo.


3. Jesu, agbelebu Re ni, 

   Ngo kan ese mi Mo; 

   Labe agbelebu Re, 

   Ngo we ese mi nu, 

   Nigbati emi o ri O,

   Ni orun rere Re:

   Nki yio dekun yin O,

   F' ogo at'ola Re. Amin

English »

Update Hymn