HYMN 314

IDAHUN (FE 337)1. MO f'ara mi fun O/Oluwa mi, 

   Sa f‘ ire Re ‘yebiye / fun mi.


2. Gbogb' ohun ti mo ni / t' ara t’okan,

   Nko je fi du o, / gba gbogbo re.


3. Sa ba mi gbe dopin / Oluwa mi, 

   Jesu, Olugbala/ Emmanuel.


4. B' akoko Ree ba de, / je ki yin O;

   Yin O nile Re / titi lailai. Amin

English »

Update Hymn