HYMN 316

1. IGBAGBO mi ri ‘bi 'sinmi

   Ibi ‘sin mi didun

   Mo gbekele Jesu Kristi 
 
   Eje Re seun fun mi.

Egbe: N ko ni s'ariyanjiyan mo 

      N ko ni se awa wi

      Pe Jesu ku fun ese mi 

      Eyi ti to fun mi.


2. O to fun mi Jesu n gbala 

   lyemeji mi tan 

   Pel'eru ese ni mo wa

   Ko si je tan mi nu. 

Egbe: N ko ni s'ariyanjiyan...


3. Okan mi ‘sin mi l'oro Re 

   Or’Olorun t’a ko

   Ooko Re l'a fi n gba ni la 

   At’eje Re pelu.

Egbe: N ko ni s'ariyanjiyan...


4. Olugbala mi n wo ni san

   O si n gbala pelu

   O t’eje Re sile fun mi

   O f’aye Re fun mi 

 Egbe: N ko ni s'ariyanjiyan mo 

      N ko ni se awa wi

      Pe Jesu ku fun ese mi 

      Eyi ti to fun mi. Amin

English »

Update Hymn