HYMN 319

C.M.S 225 P.M (FE 342)
“E korin titun si Oluwa nitori ti o 
ti se ohun iyanu" - Ps. 98:11. ALLELUYA! Allelua!! Allelua!!! 

   Ija d'opin, ogun si tan 

   Olugbala jagun 'molu 

   Orin ayo la o ma ko 

   Alleluya.


2. Gbogbo ipa n'iku ti lo 

   Sughon Kristi f'ogun re ka 

   Aiye' E ho iho ayo 

   Alleluya.


3. Ojo meta na ti koja 

   O jinde kuro n‘nu oku 

   E Fogo fun Olorun wa 

   Alleluya.


4. O d‘ewon orun apadi 

   O s'ilekun orun sile

   E korin iyin ‘segun Re 

   Alleluya.


5. Jesu nipa iya t‘o je 

   Gba wa lowo oro iku 

   K'a le ye, k‘a si ma yin O 

   Alleluya. Amin

English »

Update Hymn