HYMN 329

(FE 352)
C.M.S 230 t. H.C 577 6s. 4s
“Awon oba aiye kese jo ati awon ijoye 
ngbimo po si Oluwa" - Ps. 2:21. B‘ELESE s'owo po

   Ti nwon nde s’Oluwa 

   Dimo si Kristi Re 

   Lati gan Oba na 

   B’aiye nsata

   Pelu Esu, Eke ni nwon 

   Nwon nse lasan.


2. Olugbala joba!

   Lori oke Sion 

   Ase ti Oluwa 

  Gbe Omo Tire ro 

   Lati ‘boji

   O ni, k‘ O nde 

   K' O si goke 

   K' O gba ni la.


3. F’eru sin Oluwa 

   Si bowo f 'ase Re 

   F'ayo wa sodo Re 

   F’ iwariri duro

   E kunle fun 

   K'e teriba

   So t‘ipa Re

   Ki omo na. Amin

English »

Update Hymn