HYMN 33

C.M.S. 26 o.t. H.C. 289, CM. (FE50) 
“Ago re wonni ti Ii ewa to!” - Ps 84:1


1. OLUS‘AGUTAN eni re 

   Fi oju Re han wa, 

   Wo fun wa n'ile adura 

   M‘okan wa gbadura.


2. K‘ife ati alafia

   K'o ma gbe ile yi! 

   F’irora f'okan iponju 

   M'okan ailera le.


3. K‘a fi ‘gbagbo gbo oro Re, 

   K'a fi ‘gbagbo bebe
 
   Ati niwaju Oluwa, 

   K'a se aroye wa. Amin

English »

Update Hymn