HYMN 330

(FE 353)
K. 170 t. H. C 245 S.M
"O jinde nitori idalare wa” - Rom. 4:251. A mu ileri se 

   Ise ‘gbala pari

   Oto at'anu di ore 

   Om’Olorun jinde.


2. Okan mi yin Jesu

   T'O ru gbogb’ese re

   T’O ku f’ese gbogbo aiye

   O wa, K‘O ma ku mo.


3. Iku Re ra ‘simi 

   Fun O, l’ O ji dide

   Gbagbo, gba ekun ‘dariji 

   T‘a sa l’ami eje. Amin

English »

Update Hymn