HYMN 331

t.H.C 222 L.M. (FE 354)
"Emi li enti o mbe laye, ti o si ti ku si kiyesi,
Emi mbe laye titi loi Amin"- Ifi 1:81. JESU ore elese ku,

   Awon omo Salem nsokun 

   Okunkun bo oju orun 

   Iseti nla se lojiji.


2. Nihin l’a r’anu at’ife 

   Oba ogo ku f ’enia

   Wa! ayo kil’ a tun ri yi 

   Jesu t’O ku tun ji dide.


3. Ma beru, "Oba, wa titi 

   Iwo t’a bi lati gba wa”

   K’e b’iku pe, ”Oro re da? 

   "Iboji, isegun re da?"


4. E wipe, “Oba, wa titi,

   Iwo ta bi Iati gba wa,"

   K’e b’iku pe, “Oro re da?” 

   “iboji, isegun‘re da?” Amin

English »

Update Hymn