HYMN 333

(FE 356)
E.O. 158 C.M.S 218 6s. 8s
"Iwo ti di igbekun ni igbekun lo”
 - Ps. 68:181. OORO ayo na de

   Olugbala bori

   O fi ‘boji sile

   Bi Olodurnare.

Egbe: A d’igbekun ni’gbekun lo, 

      Jesu t'o ku di alaye.


2. Onigbowo wa ku 

   Tani to fi wa sun? 

   Baba dawa lare 

   Tal' o to da ebi?

Egbe: A d’igbekun...


3. Kristi tisan gbese 

   Ise ogo pari

   O ti ran wa lowo 

   O ti ba wa segun.

Egbe: A d’igbekun ni’gbekun lo, 

      Jesu t'o ku di alaye. Amin

English »

Update Hymn