HYMN 334

8s 75s (FE 357)
Tune: ‘E gbohun ife at‘anu1. ALLELUYAH! O ti jinde 

   Jesu goke lo s'orun

   O si fo itegun esu

   Angeli ho, enia dahun.

Egbe: O ti jinde, O ti jinde 

      O Wa laye, ko ku mo.


2. Alleluyah! O ti jinde 

   Eniti o ga julo

   Jeri si Emi na wipe

   On ni alagbawi wa,

Egbe: O ti jinde, O ti jinde fun

      Awa t'a da lare.


3. Alleluyah! O ti jinde 

   lku ko tun n‘ipa mo 

   Kristi papa ni Ajinde 

   Yio si m‘awon Tire wa. 

Egbe: O ti jinde, O ti jinde fun

      Oluwa Oba Iye. Amin

English »

Update Hymn