HYMN 339

P.& MP 116 (FE 362)
"Lehin eyi, O fi ara han fun awon 
meji" - Marku 16:121. MO gbo Jesu wipe 

   ‘Agbara re kere, 

   Alare, sora gbadura 

   Pipe re mbe lodo mi.

Egbe: Jusu san gbogbo 

      Gbese ti mo je

      Ese ti m'abawon wa 

      O fo mi fun bi nso.


2. Oluwa toto mo mo 

   P’agbara Re nikan 

   Le s’adete di mimo 

   O le m’okan lile ro.

Egbe: Jusu san gbogbo...


3. "Gbati ‘pe ‘kehin ba dun 

   T’o npe mi s’odo Re

   Jesu ti san gbogbo re,

   Em’ o ba goke orun.

Egbe: Jusu san gbogbo 

      Gbese ti mo je

      Ese ti m'abawon wa 

      O fo mi fun bi nso. Amin

English »

Update Hymn