HYMN 34

C.M.S. 28 o.t. H.C 167, SM. (FE 51) 
"Nwon nkigbe Ii ohun rara wipe
yio ti pe lo, Oluwa?” - lfihan 6:10


1. A BE a fe ri O, 

   Ojo ‘simi rere 

   Gbogbo ose a ma wipe 

   lwo o ti pe to?

2. O ko wa pe Kristi 

   Jinde ninu oku 

   Gbogbo ose a ma wipe 

   Iwo o ti pe to!


3. O so t’ajnde wa

   Gege bi ti Jesu, 

   Gbogbo ose a ma wipe, 

   Iwo o ti pe to!


4. Iwo so t’ isimi

   T’ilu alafia 

   Ti’ibukun enia mimo 

   Iwo o ti pe to. Amin

English »

Update Hymn