HYMN 345

(FE 368)
t.H.C 204 6s. 8s
"E ho iho ayo si Oluwa, enyin ile
gbogbo" - Ps. 100:11. OLORUN goke lo 

   Pelu ariwo nla 

   Awon ipe orun

   Nfi ayo Angeli han.

Egbe: Gbogbo aiye yo, k'e gberin

      E f'ogo fun Oba Ogo.


2. O j’enia laiye 

   Oba wa ni loke 

   Ki gbogbo ile mo 

   lfe nla Jesu wa.

Egbe: Gbogbo aiye yo...


3. Baba fi agbara, 

   Fun Jesu Oluwa 

   Ogun Angeli mbo O 

   On l'Oba nla Orun.

Egbe: Gbogbo aiye yo...


4. L'or’ite re mimo 

   O gb‘opa ododo 

   Gbogbo ota Re ni 

   Yio ka lo bere.

Egbe: Gbogbo aiye yo...


5. Ola Re l’ota wa 

   Esu, aiye, ese

   Sugbon y'o r‘ehin won 

   ljoba Re y'o de.

Egbe: Gbogbo aiye yo, k'e gberin

      E f'ogo fun Oba Ogo. Amin

English »

Update Hymn