HYMN 353

(FE376)
CM.S 425. H.C 560 C.M
"Opolopo enia ti enikeni ko le ka 
iye duro niwaju ite” - Ifi. 7:91. E WA k’a da orin wa po 

   Mo t‘awon Angeli 

   Egbegberun ni ohun won 

   Okan ni ayo won.


2. Nwon nkorin pe, ‘Ola-nla ye 

   Od-agutan t'a pa

   K’a agberin pe “Ola-nla ye" 

   Tori O ku fun wa.


3. Jesu, li O ye lati gba

   Ola at’agbara 

   K’iyin t’enu wa ko le gba 

   Je Tire, Oluwa.


4. K'awon t’o wa loke orun 

   At’ile at'okun

   Dapo lati gb'ogo Re ga 

   Jumo yin ola Re.


5. Ki gbogbo eda d'ohun po 

   Lati yin oruko

   Enit’ o joko lor’ite 

   Ki nwon si wole fun. Amin

English »

Update Hymn