HYMN 355

1. Gba ti ipe Oluwa ba dun t‘aye yoo 

   si fo lo Ti imole ojo titun yoo si de

   Nigba ti awon omo igbala ba pejo l'oke 

   T’a ba si p‘oruko lohun, n o wa n’be.

Egbe: Gba t'a ba p’oruko lohun 

      Gba t'a ba p’oruko Iohun 

      Gba t'a ba p'oruko lohun

      Gba t’a ba p'oruko Iohun

      n o wa n’be.

2. L'ooro ayo naa t‘awon oku n‘nu 

   Kristi yoo jide

   Ti won yoo si pin n‘nu ogo ajinde

   Gba ti awon ayanfe yoo pejo 

   si oke orun T‘a ba si p‘oruko 

   l‘ohun, n o wa n'be.

Egbe: Gba t'a ba p'oruko lohun...


3. Je ki a fi gbogbo akoko wa s'ise 

   f'Oluwa. Jeki a rohin ife iyanu Re

   Nigba ti a ba si pari ire-ije wa l’aye 

   T'a ba si p’oruko l’ohun, n o wa n'be

Egbe: Gba t'a ba p’oruko lohun 

      Gba t'a ba p’oruko Iohun 

      Gba t'a ba p'oruko lohun

      Gba t’a ba p'oruko Iohun

      n o wa n’be. Amin

English »

Update Hymn