HYMN 36

(FE 53)
C.M.S. 32, K. 125, t.H.C 332 C.M.
"Nibe li alare wa ninu isimi" - Job 3:17


1. NlGBAWO Olugbala mi, 

   L'emi o ri O je?

   N'isimi t'o ni ibukun, 

   Laisi ‘boju larin.


2. Ran mi lowo n‘irinkiri 

   L’aiye aniyan yi;

   Se mi ki nfi ‘fe gbadura, 

   Si gha adura mi.


3. Da mi si, Baba, da mi si 

   Mo f’ara mi fun O

   Gba ohun gbogbo ti mo ni, 

   Si f‘ara Re fun mi.


4. Emi re, Baba, fifun mi,

   K‘o le ma pelu mi,

   K'o se imole ese mi,

   S'isimi ailopin. Amin
English »

Update Hymn