HYMN 364

(FE 386) C.M.S 414 S.M H.C 410 
S.M
"Awon eni, nipa igbagbo ati suru 
ti o jogun ilerli wonni" - Heb. 6:121. F’AWON enia Re,

   T'o ti fi aiye sile

   Awon to mo O, t’ o sin O, 

   Gba orin iyin wa.


2. F’awon enia Re

   Gba ohun ope wa

   Awon t’o fi O s’esan won 

   Nwon ku n‘gbagbo Re!


3. Ni gbogbo aiye won 

   ‘Won ni nwon nwo l'oju 

   Emi Mimo Re l’onko won 

   Lati s‘ohun gbogbo.


4. Fun eyi, Oluwa,

   A nyin oruko Re

   Je k‘a ma tele iwa won

   Ki a le ku bi won. Amin

English »

Update Hymn