HYMN 369

(FE 391) C.M.S 251 H.C L.M
"Baba, emi fe ki awon ti lwo fi fun
mi ki o wa peIu mi nibiti emi gbe 
wa” - Job. 17:24


1. JE ki m'nipo mi lodo Re 

   Jesu, lwo isimi mi

   ‘Gbana l‘okan y’o simi

   Y'o si ri ekun ‘bukun gba.


2. Je ki m’ n'ipo mi lodo re 

   K’emi ko le ri ogo Re 

   ‘Gbana ni okan etan mi 

   Yio ri eni f'ara le.


3. Je ki m’ n’ipo mi lodo Re 

   Nibi awon mimo nyin O 

   ‘Gbana ni okan ese mi

   Y’o dekun ese ni dida.


4. Je ki m'n’ipo mi lodo Re 

   Nibi a ki yipo pada

   Nib’a ko npe, o digbose 

   Titi aiye, titi aiye. Amin

English »

Update Hymn