HYMN 370

C.M.S. 254 8s. 8s. 6s (FE 392)
“Awa nyo ni ireti Ogo Olorun"
 - Rom. 5:21. LEHIN aiye buburu yi 

   Aiye ekun on osi yi

   Ibi rere kan wa

   Ayipada ko si nibe

   Ko s’oru af'osan titi 

   Wi mi, ‘wo o wa nibe?


2. “Lekun ogo re ti m’ese" 

   Ohun eri ko le we ‘be

   Lati b‘ewu re je 

   L’ebute daradara ni,

   A ko ni gburo egun mo 

   Wi mi, ‘wo o wa nibe?


3. Tani o de ‘be? Onirele 

   To f'iberu sin Oluwa

   T'won ko nani aiye

   Awon t'a f'Emi Mimo to 

   Awon t‘o nrin l’ona toro 

   Awon ni o wa nibe? Amin

English »

Update Hymn