HYMN 371

1. OJO nla kan n bO wa 

   Ojo nla kan n bo

   Ojo nla kan bo wa nigboose

   T’awon eniyan mimo at'elese 

   yoo pinya lwo ha setan fun ojo naa.

Egbe: O ha setan? O ha setan

      O ha setan fun ojo 'daju

      O ha setan? O ha setan

      Fun ojo nla naa.


2. Ojo didan kan n be 

   Ojo naa n bo wa

   Ojo didan kan n bo nigbaoose 

   Sugbon didan re je ti awon t'o 

   fe Oluwa lwo ha setan fun ojo naa.

Egbe: O ha setan? O ha setan...


3. Ojo ‘banuje n bo

   Ojo naa n bo wa

   Ojo ‘banuje n bo nigboose 

   T’elese yio gbo pe, E to, Emi ko 

   mo yin ri

   Iwo ha setan fun ojo naa.

Egbe: O ha setan? O ha setan

      O ha setan fun ojo 'daju

      O ha setan? O ha setan

      Fun ojo nla naa. Amin

English »

Update Hymn