HYMN 375

t.H.C 255 C.M 
"Okan mi le mo erupe so mi di aye
gege bi oro re" - Ps. 119:251. EMI mimo, ‘daba orun 

   Wa li agbara Re

   K’o da ina ife mimo 

   Ni okan tutu wa.


2. Wo b' a ti nrapala nihin 

   T'a fe ohun asan 

   Okan wa ko le fo k‘o lo 

   K’o de ‘bayo titi.


3. Oluwa, ao ha wa titi 

   Ni kiku osi yi?

   lfe wa tutu be si O 

   Tire tobi si wa.


4. Emi Mimo ‘daba orun 

   Wa ni agbara Re

   Wa dana ‘fe Olugbala 

   Tiwa o si gbina. Amin

English »

Update Hymn