HYMN 376

(FE 397)
C.M.S 432 t.H.C 41. C.M
"Jakobu yio ha se le dide?" - Amos 7:21. "TANI o gbe Jakob dide” 

   Ore Jakob ko po; 

   Eyi t’o je ‘yanu ni pe 

   lmo won ko s’okan.


2. “Tani o gbe Jakob dide” 

   Ota Jakob nipa

   Mo r’ayo ‘segun loju won 

   Nwon ni, o pari fun.


3. Tani o gbe Jakob dide 

   A ha r’eni le wi?

   E ka to ro nibule yi 

   O ha tun le ye mo?


4. Oluwa mi, ise Re ni! 

   Ko s’eniti o le se 

   Se b’iri s’ori Jakobu, 

   On yio si tun ye. Amin

English »

Update Hymn