HYMN 382

H.C 250 t.H.C 16 L.M (FE 404) 
"Nitori aiye yio kun fun imo Oluwa 
bi omi ti bo okiun“ - Isa. 11:91. EMI anu, oto, ife

   Ran aghara Re t‘oke wa 

   Mu iyanu ojo oni

   De opin akoko gbogbo.


2. Ki gbogbo orile ede 

   Ko orin ogo Olorun

   Ki a si ko gbogbo aiye 

   N'ise Olurapada wa.


3. Olutunu at'Amona 

   Joha ijo enia Re

   K'araiye mo ibukun Re 

   Emi anu, oto, ife. Amin

English »

Update Hymn