HYMN 385

(FE 407)
C.M.S 275 H.C 254 L.M
“lye awon ti a fi Emi Olorun to awon
ni Ise omo Olorun” - Rom. 8:14


1. EMI Mimo 'Daba orun

   Wa mu itunu sokale 

   Se Oga at’Oluto wa,

   Ma pelu gbogbo ero wa.


2. Jo, fi Otito Re han wa 

   K’a le fe k'a si m'ona Re 

   Gbin ife toto s'okan wa 

   K’a ma le pada lehin Re.


3. Mu wa k’a to ona mimo 

   T‘a le gba d‘odo Olorun 

   Mu wa to Kristi, Ona lye 

   Ma je ki awa sina Io.


4. Mu wa t’Olorun simi wa

   K'a le ma ba gbe titi lai

   To wa s‘orun, k’a le n'ipin 

   L'owo otun Olorun wa. Amin

English »

Update Hymn