HYMN 386

(FE 409)
H.C 251 t.H.C 113. C.M
"Lojiji iro si iri orn wa, bi iro efufu 
IiIe” - Ise. 2:21. 'GBANI t‘Olorun sokale 
  
   O wa ni ibinu 

   Ara si nsan niwaju Re 

  Okunkun on ina.


2. Nigbat‘o wa nigba keji 

   O wa ninu ife

   Emi, Re si ntu ni lara 

   B'afefe owuro.


3. Ina Sinai ljo kini 

   T’owo re mbu soke 

   sokale jeje bi ade

   Si ori gbogbo won.


4. Bi ohun eru na ti dun

   Leti Israeli

   Ti nwon si gbo iro ipe

   T‘o m'ohun angeli gbon.


5. Be gage nigbat' Emi wa, 

   Ba le awon Tire

   lro kan si ti orun wa 

   Iro iji lile.


6. O nkun, ife Jesu, o nkan

   Aiye ese yika 

   L'o kan alaigboran nikan 

   Ni aye ko si fun.


7. Wa, Ogbon, ife, at'lpa 

   Mu ki eti wa si

   K'a ma so akoko wa nu

   Ki ‘fe Re le gba wa. Amin

English »

Update Hymn