HYMN 388

H.C. 39 7s. 5 (FE 411)
"Awon eni-irapada Oluw yio pada nwon
o si wa si Sioini ti awon ti orin...ikanu
ati afe yio fo lo" - Isaiah 51:111. OLORUN Metalokan

   Oba ile at’okun

   Gbo ti wa bi a ti nko 

   Orin iyin Re.


2. ‘Wo imole, l'owuro 

   Tan mole Re yi wa ka 

   Je ki ebun rere Re

   M’aiya wa bale.


3. Wo ‘mole, nigb‘orun wo, 

   K'a ri idariji gba;

   Ki alafia orun

   F‘itura fun wa.


4. Olorun Metalokan! 

   Isin wa laiye ko to!

   A nreti lati dapo

   Mo awon t'orun. Amin

English »

Update Hymn